ÌJỌ ÀPỌ́SÍTÉLÌ KRISTI Naijiria àti Oke Okun OMI IYE NAA, (January- December, 2023 ỌJỌBỌ (Thursday) August 3, 2023 ÀKÒRI: MAṢE FỌNNU NIPA ỌJỌ ỌLA (1)

ÌJỌ ÀPỌ́SÍTÉLÌ KRISTI 

Naijiria àti Oke Okun

OMI IYE NAA, (January- December, 2023

ỌJỌBỌ (Thursday) August 3,  2023

ÀKÒRI: MAṢE FỌNNU NIPA ỌJỌ ỌLA (1)

AKOSORI:MÁṢE leri ara rẹ niti ọjọ ọla, nitoriti iwọ kò mọ̀ ohun ti ọjọ kan yio hù jade (ÌWÉ ÒWE 27:

KA

JAKỌBU 4:13-1

[13].  Ẹ wá nisisiyi, ẹnyin tí nwipe, Loni tabi lọla awa ó lọ si ilu bayi, a o si ṣe ọdún kan nibẹ, a o si ṣòwo, a o si jère

[14].  Nigbati ẹnyin kò mọ̀ ohun ti yio hù lọla. Kili ẹmí nyin? Ikũku sá ni nyin, ti o hàn nigba diẹ, lẹhinna a si túka lọ

[15].  Eyi ti ẹ bá fi wipe, bi Oluwa ba fẹ, awa o wà lãye, a o si ṣe eyi tabi eyini

[16].   Ṣugbọn nisisiyi ẹnyin nṣeféfe ninu ifọnnu nyin: gbogbo irú iṣeféfe bẹ̃, ibi ni

[17].   Nitorina ẹniti o ba mọ̀ rere iṣe ti kò si ṣe, ẹ̀ṣẹ ni fun u

AKOR

MASE FONNU NIPA OJO OLA(I

ITUPA

      O ha jẹ ohun ti o lodi fun awon Kristiẹni lati ṣeto bi? Rara. Ohun ti Jakobu ori kerin kilo lodi si ni pe ki a maa gbe igbe-aye  wa, ki a si maa seto bii pe ko si Ọlọrun. Iru eyi maa n yọrisi hihuwa aigbagbọ pe Ọlọruun  n bẹ ni ọna afojuri. Bi aye ti rọrun to ko rọrun to bi a ti lero. Ọlọrun ni yoo mojuto rere, buburu ati aidara ọjọ ọla. Ikilọ jakọbu gan-an nihin kii ṣe ipọnju lati jere ninu owo, bee ni kii ṣe pe o n bu ẹnu atẹ lu ifọgbọn seto, ṣugbọn dipo bẹẹ, ero iṣiwere to jẹ abuda iṣeto awọn eniyan ti ko ni Ọlọrun  ninu rẹ. O wi pe, eyi ti ẹ ba fi wi pe bi Oluwa ba fẹ, awa o wa laaye, a o si ṣe eyi tabi eyini (Jak.4:15

      Onkọwe iwe-Owe 16:3 gbani niyanju, ko iṣẹ rẹ ( igbesẹ) le Oluwa lọwọ, a o si fi idi iro-inu (eto) rẹ  kalẹ (ṣaṣeyọri). Awọn onigbagbọ ninu Ọlọrun ko ni lati maa fọnnu nipa ohunkohun paapaa julọ aṣeyọri nitori itumọ  eyi ni igberaga ati ironu asan. lwe-Mimo wi pe, Nitori tani o mu o yatọ? Kin ni iwọ si ni ( talẹnti, isura, anfaani abbl) ti iwọ ko ti i gba. Nje bi iwọ ba si ti gba a, e ha ti ṣe ti iwọ fi n halẹ bi ẹni pe iwọ ko gba a? ( 1 Kor 4:7). Fi gbogbo iyin ati ogo fun Ọlọrun, olufunni ni ohun gbogbo, ninu ohun yowu ti o ba n ṣeto tabi gbeero. Kọ ẹkọ lati inu owe Ọkunrin ọlọrọ ni Luku 12:15-20. Jakọbu ṣe ikilọ pe, ṣugbọn ni sinsin yii ẹyin n ṣefefe ninu ifọnnu yin,    gbogbo iru iṣefefe bẹẹ ibi bi Ara, ẹ jẹ  ki a ṣiwo gbigbe ni (Jak. 4: 1 6) bii alaigbagbọ ti o n pe ara rẹ ni  Kristiẹn

Awọn Koko Adur

1.   Oluwa, igbagbọ mi rọ mọ Ọ; Mo mọ pe ọjọ iwaju mi laabo ninu R

2.   N ko ni agbara temi, Mo jẹwọ fun Ọ, Jesu: N ko ni agbara tem

3.   Gbadura pe awọn ọlọla ati olokiki to wa laarin wa ko nii gberaga nitori awọn anfaani ti Ọlọrun fun wọn ju awọn ẹlomiran l

Orin Ti A Dabaa, I.O.  CAC: 8

OKOOLELẸGBẸRIN O LE KA

                 6.6.4.6.6.6.4

Oju wa nwo Oluwa Ọlọrun wa.  OD. 123:2

1. lgbagbo mi wo O

   Iwo Od'agutan

   Olugbala,

   Jo, gbo adura mi,

   M'ese mi gbogbo lo;

   K'emi lat'oni lo

   Si je Tire.

2. Ki ore-ofe R

   F'ilera f'okan mi;

   Mu mi tara;

   B'Iwo ti ku fun mi,

   A! K'ife mi si O

   K'o ma gbona titi

   B'ina iye.

3. 'Gba mo nrin l'okunku

   Ninu ibanuje,

   S'amona mi;

   So okun di 'mole;

   Pa 'banuje mi re,

   Ki nma sako kuro

   Li odo Re

4. Gba ti aye ba pin

   T'odo tutu iku

   Nsan l'ori mi,

   Jesu, ninu ife,

   Mu k'ifoya mi lo,

   Gbe mi d'oke orun

   B'okan t'ara.

Amin

Afikun Ibi Kika Fun On

Owe 27:11-30:33ÌJỌ ÀPỌ́SÍTÉLÌ KRISTI

Naijiria àti Oke Okun

OMI IYE NAA, (January- December, 202

Ò

ỌJỌBỌ (Thursday) August 3,  2023

ÀKÒR

MAṢE FỌNNU NIPA ỌJỌ ỌLA (1)

AKOSOR

    MÁṢE leri ara rẹ niti ọjọ ọla, nitoriti iwọ kò mọ̀ ohun ti ọjọ kan yio hù jade (ÌWÉ ÒWE 27:

K

Owe 27:11-30:33i:.      ,       n       e       . ..N21ọ.i.ẹ.a i.).LE)I:. . . . : 7A:1)I: Í:.jọ3)  i:.      ,       n       e       . ..N21ọ.i.ẹ.a i.).LE)I:. . . . : 7A:1)I: Í:.jọ3) t'ara. 

Amin.

Afikun Ibi Kika Fun Oni:

Owe 27:11-30:33

Previous Post Next Post